Ise Awon aposteli(Acts 7:54-60,8:1&3) ni a o ti wo ohun ti o şele si Stefanu; omo ehin ti o kun fun agbara ati emi mimo bi o ti tu oro oore-ofe jade lati enu re s'ori awon ti o pa a ti Poolu si je okan ni be.....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻......

Kan si wa l'ori:
[email protected]
+447459913053