A ko le ko eko yi lai wo igbesi aye ogbontarigi iranşe Olorun ati ajumo jogun pelu Kristi; aposteli Poolu...awon idojuko re ti o le ko irewesi ba eniyan...sugbon Poolu tesiwaju bi akoni ogun Kristi......Korinti keji, ori kokanla(2 Corinthians 11:25-27, 29....12:10)....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻

Kan si wa l'ori
[email protected]
+447459913053