Niwon bi adura ti je ona ti Olorun la s'ile lati le takoroso pelu re, o n reti pe ki a wa a tokan-tokan ni fifi adura se esi akoko fun awon iberu/ipaya wa, idojuko, ipenija ati italaya wa pelu tori o ti se ileri lati da wa l'ohun....Jeremiah 33:3.....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻........

Kan si wa ni ori:
[email protected]
+447459913053