Luku 18:1...Ninu atotonu/itakoroso mi pelu òpò eniyan ni mo ti s'akiyesi pe; adura je ohun ti a maa s'oro nipa pupo sugbon ti a kii gba bi oro ba doju e tan....awon miiran a gbaa, sugbon won a si tete rewesi. Kini idi re ti o fi ri be e?🤔.....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻.....

Kan si wa l'ori:
[email protected]