Kiki bi o ba ti wa ni apa ibi ififunni ri, a ni ti o je olufunni; ni o le je ki alaye eko tubo ye o ore mi....paapaa nigbati eni naa tabi awon eniyan ti o fi ebun re fun ko ba ka o si, ti won fi oju bintin re tabi foju pa o re🤔🤔.....D'arapo mo wa fun eko ti oni....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👨‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻

Kan si wa l'ori:
[email protected]
+7459913053